Stephen Olushola Oladosu - Ojo Aanu lyrics

Published

0 96 0

Stephen Olushola Oladosu - Ojo Aanu lyrics

Chorus Ojo aanu a ro le mi lori, Ojo ibukun latodo baba a, ati si ferese orun sile lemi lori, odo aye mi koni gbe. Stz1 Ope ti mo ti n bere ibukun owo laye, ope ti mo ti n bere omo rere lodo Re, ileri ayo ti Baba se koma ni lo laise, nitori naa mo gba gbo pe ma ri temi se. Stz2 Ope ti mo ti n bere ibunkun ile laye, ope ti mo ti n bere igebga lodo Re, ileri ayo ti Baba se koma ni lo laise, nitori naa mo gba gbo pe ma ri temi se. Stz3 Ope ti mo ti n bere ibunkun ise laye, ope ti mo ti n bere isegun lodo Re, ileri ayo ti Baba se koma ni lo laise, nitori naa mo gba gbo pe ma ri temi se. Stz4 Ope ti mo ti n bere fun aya rere laye, ope ti mo ti n bere oko rere lodo Re, ileri ayo ti Baba se koma ni lo laise, nitori naa mo gba gbo pe ma ri temi se. Chorus Rain of mercy will fall upon my head, Rain of blessing from father above, windows of heaven has been opened up upon my head, River of my life won’t run dry. Stz1 I’ve been asking you for long for financial blessing, I’ve been asking you for long for fruit of the womb, the promise of joy made by father will not go unfulfilled, therefore I have faith that my case has been settled. Stz2 I’ve been asking you for long for blessing of a house, I’ve been asking for long to have my promotion, the promise of joy made by my father will not go unfulfilled, therefore I have faith that my case has been settled. Stz3 I’ve been asking you for long for the blessing of good job, I’ve been asking for long for victory from you, the promise of joy made by father will not go unfulfilled, therefore I have faith that my case has been settled. Stz4 I’ve been asking for long for a God fearing wife, I’ve been asking for long for a God fearing husband, the promise of joy made by father will not go unfulfilled, therefore I have faith that my case has been settled.