LYRICS.AZ APPLICATION

Download from Apple Store
Download from Google Play

Sola Allyson - Alujanjankijan lyrics


Feat : Adekunle Gold

Iya, Iya ta'kun wa'le

Alujanjankijan

Iya, Iya ta'kun wa'le

Alujanjankijan

E ma f'omo s'ile fun'ya je

Alujanjankijan

Eni t'o bi'mo lo ye k'o w'omo

Alujanjankijan

Ba mi n'omo mi, o ye k'o de'nu olomo

Oju merin lo n bi'mo, sugbon, igba oju li n w'omo

Omo t'a o ko, a gbe'le t'a ko ta

Omo t'a o to, a k'eso t'a ni ta

Omo n'igbeyin, omo l'ola, omo l'ola, omo n'iyi, omo l'ade

Omo l'ewa, omo l'eso oh ohhh

O da a, bi o da a- o le da a; o san, bi o san- a de san

Igboya at'adura ni o gba- yi o da ahhh

Iya, Iya ta'kun wa'le

Alujanjankijan

Iya, Iya ta'kun wa'le

Alujanjankijan

E ma f'omo s'ile fun'ya je

Alujanjankijan

Eni t'o bi'mo lo ye k'o w'omo e; e t'omo

Alujanjankijan

Ori fun wa l'omo're bi i ti Samuel oh

Won ko Samu, o gb'eko oh, o si se'hun rere

If you spare the rod, you go spoil the child; I hope you know?

Train them with the love of God; abegi oh

Tori, alaigboran omo- asa ni

Agba o kunwo l'oju- asa ni

Agba o jo won l'oju oh- asa ni

Agba iya ni o da- asa ni

Alalugboran omo oh- omo ni

Won le d'eyan l'ola- omo ni

T'a ba to won daada o- omo ni

[Lyrics from: https:/lyrics.az/sola-allyson/-/alujanjankijan.html]
Won le d'eyan l'ola

Iya, Iya ta'kun wa'le oh

Alujanjankijan

Iya, Iya ta'kun wa'le oh

Alujanjankijan

Eni t'o bi'mo lo ye k'o w'omo oh

Alujanjankijan

E ma f'omo s'ile fun'ya je oh

Alujanjankijan

Iya, Iya ta'kun wa'le oh ohh

Alujanjankijan

E ma f'omo s'ile fun'ya je ohh

Alujanjankijan

Eni t'o bi'mo e lo ye k'o w'omo e; e t'omo

Alujanjankijan

Iya, baba, t'akun wa'le

Alujanjankijan

Kekere la ti n pe'ka iroko, t'o ba d'agba tan, ebo ni o ma gba

Ohun t'a ba fi s'ile l'ewure n gbe; k'ewure aye ma ma gbe wa l'omo lo

Omo t'a o ba to, ekun aye a gbe lo; k'ekun aye ma ma gbe wa l'omo lo

Iya, Iya ta'kun wa'le

Alujanjankijan

Iya, Iya ta'kun wa'le oh ohh oh oh- Alu jan jan jan jan jan jan jan

Iya, Iya taaaaaaaaaa [Alujanjankijan] ‘kun

Iya, Iya ta'kun wa'le oh- Alujanjankijan

Edumare, k'o ba wa t'omo wa oh- Alujanjankijan

Edumare, k'o ba wa t'omo wa oh

Children are the heritage of the Lord oh

Alujanjankijan

E gbo! Omo l'ola, omo l'aye [Alujanjankijan]; omo l'ewa

Omo l'ere, k'a f'aye s'ile, k'a t'omo wa ohh

Alujanjankijan

They are the future generation

Alujanjankijan

Iya, Iya ta'kun wa'le

Alujanjankijan

Correct these Lyrics