Lagbaja - Emi Mimo lyrics

Published

0 357 0

Lagbaja - Emi Mimo lyrics

Emi Mimo, so kale Emi Mimo, sori mi Emi Mimo, latoke wa Fokan mi, se bugbe Fokan mi, se bugbe re Emi Mimo, ba le wa Emi Mimo, sile wa Emi Mimo, latoke wa File wa, se bugbe File wa o, se bugbe re Emi Mimo, so kale Emi Mimo, silu wa Emi Mimo o, latoke wa Filu wa, se bugbe Filu wa o, se bugbe re Fopin si Rudurudu Rederede Radarada Rederede Hilahilo hilahilo hilahilo Gbogbo aye nte siwaju Kawa naa ba won te Emi mimo nikan lole se Ba gbeke le omo Adamo Ee otubante Igi ti a feyin ti O fe wo luni pa Awe dakun ba mi feju O buta senu E jowo e kin wa leyin Won yegun sowo Be olojo o dekun kika Ekolo iboji Won nreti ran ara yi Ojo nlo ojo nlo ojo nlo Emi mimo, so kale Emi mimo, saye won Emi mimo o, latoke wa Fokan won, sebugbe Fokan won o, sebugbe re