Keziah Jones - L'oke Ati Petele lyrics

Published

0 713 0

Keziah Jones - L'oke Ati Petele lyrics

L'oke ati petele L'oke ati petele Nibe la gbe bi mi si o, Ibe la gbe tomi dagba o, Ile ominira Emi yo fi abeokuta shogo, Ma duro lori olumo, Mayo loruko egba o Emi omo lisabi. Mayo mayo mayo ooo, Lori olumo Mayo mayo mayo ooo, Lori olumo Abeokuta ilu egba Nko ni gbagbe re, Nko ni gbagbe re, Bi ilu odo oya. Emi yo fi abeokuta shogo, Ma duro lori olumo, Mayo loruko egba o Emi omo lisabi. Mayo mayo mayo ooo, Lori olumo Mayo mayo mayo ooo, Lori olumo