RAZZYKAPOR - Beast In The Game Lyrics(SNIPPET) lyrics

Published

0 204 0

RAZZYKAPOR - Beast In The Game Lyrics(SNIPPET) lyrics

Toba ni kin mu enu le rap,oma yami lara.... Ti mi se ti fi blow gangan lo ma n Kami lara....... Aimoye show timo ti lo ti won ti da ebu simi lara.... Ebu yen po ni mose tepa morin Kara kara...... Once upon a time won ni awon gbo nipa rapper kan.... To gba ijoba music to tu take over alaba gan...... To ba wunmi ma si ogun wole pelu okada kan..... Kode si eni tole bami po even koje Obama gan... Official lyrics set to drop soon stay tuned