Olamide - Sterling Environmental Makeover (STEM) lyrics

Published

0 2000 0

Olamide - Sterling Environmental Makeover (STEM) lyrics

[Intro] As you all know It’s Young John the wicked producer We did this cause we care “we careee eeh” We care for the people eeh! We care for the environment aah! and we care for the world [Hook/Chorus] Nani nani nani Ohun ani lan nani “Nani” Spread love to your friends and family Sterling environmental makeover All over the world, create great example Imototo lo le segun arun gbogbo Imototo lo le segun arun gbogbo Imototo ile, imototo ara Imototo lo le segun arun gbogbo [Bridge] Won ni ko gbale “gbale”, nule “nule”, fo ile “fo ile”, Repeate Won ni ko gbale “gbale”, nule “nule”, fo ile “fo ile”, Repeate Won ni ko gbale “gbale”, nule “nule”, fo ile “fo ile”, Repeate Won ni ko gbale “gbale”, nule “nule”, fo ile “fo ile”, stop shay be [Verse 1] Agba kin wa l’oja k’ori woo ooh B’omode ge gi, agba lo ma gba ta re bo ooh Bo se ni kin kede fu yin , fuyin pelemo ooh Pelemo, to ni le t’alejo ke gbo ooh Peace and Unity, Love and Honesty No calamity, iyen gangan lo correcty Hausa ti Igbo, Yoruba ka connecti yeeh ka connecti, iyen gangan lo correcti [Hook/Chorus] Nani nani nani Ohun ani lan nani “Nani” Spread love to your friends and family Sterling environmental makeover All over the world, create great example Imototo lo le segun arun gbogbo Imototo lo le segun arun gbogbo Imototo ile, imototo ara Imototo lo le segun arun gbogbo [Bridge] Won ni ko gbale “gbale”, nule “nule”, fo ile “fo ile”, Repeate Won ni ko gbale “gbale”, nule “nule”, fo ile “fo ile”, Repeate Won ni ko gbale “gbale”, nule “nule”, fo ile “fo ile”, Repeate Won ni ko gbale “gbale”, nule “nule”, fo ile “fo ile”, stop shay be [Verse 2/Outro] Omi baba mi kan lailai, omi babami kan lailai Eja ropoti lowan be, Naija ori yin o wan be Africa is my fatherland, Nigeria is my country ooh Sanu de zuwa “sanu de zuwa” Kedu o kodi “Kedu o kodi” Igama Nigeria “igama Nigeria” Ko ni re body “ko ni re body ooh” Ba ni a so ko s’oja, a ba ara ile Surulere ooh, ka ma ba ra wa se