Brymo - Bá’núsọ lyrics

Published

0 1711 0

Brymo - Bá’núsọ lyrics

{Verse 1 – Brymo} Abéré á lo Abéré á lo K’ó nà okùn ó tó dí ò A ò ní dé bá won A ò ní dé bá won Ení bá ní a máà de ò {Chorus – Brymo} Bá’núso Bá’núso Má b’enìyan só Bá’núso Bá’núso Má b’enìyan só {Verse 2 – Brymo} Omijé á gbe Omijé á gbe Ìbànújé á dèrin ò Eniafé Eniafé lamò o A ò mo’ni tó fé ni ò {Chorus – Brymo} Bá’núso Bá’núso Má b’enìyan só Bá’núso Bá’núso Má b’enìyan só {Verse 3 – Brymo} Ení bá ma b’ésù jeun Síbíi rè á gùn gan Eni ò mò áù Ówá jeé Òsèlú mà ló layé ò {Chorus – Brymo} Bá’núso Bá’núso Má b’enìyan só Bá’núso Bá’núso Má b’enìyan só {Verse 4 – Brymo} Èyin ará Ewá gbó òò Òrò kan se ùrùn ùrùn nínú iii Sé kín só Kín só Ká bá’núso {Chorus/Outro – Brymo} Bá’núso N’òní b’enìyan só Bá’núso Bá’núso Má b’enìyan só Bá’núso Bá’núso Má b’enìyan só