Bisade Ologunde - Faa-To lyrics

Published

0 167 0

Bisade Ologunde - Faa-To lyrics

Omo te nwo yi, Ko ma se ipanle Kii se pa mi nku sori benbe soko Mo ko loro o Ewo, ewo, ewo, ewo ewo pounbele To…omo temi kii jefoti - Fa …To! Omo temi kii jepa – Fa…To! Omo temi kii jegbarun – Fa…To! Omo temi ije beliti – Fa…To! To ba mo pe o fe gba boolu O ba kori si papa Gboju oke.. ko wo mi loju En… wo mi loju Oju loro wa Gbogbo wa mo lo fe Tebitebi lo faya Woo… ebi nle repete O ye abi o ye? O ye abi o ye? So moriki re- Jenke So moriki re –Jenke To ba ti mo poo le ke o Fododo mi le jeje o Feyinju mi le jeje o FAjike mi le jeje o FAmope mi le jeje o FAmoke mi le jeje o Fi Jenke mi le jeje jeje jeje E dakun e moo da mi lohun Baa se nkira wa ni city wa En Odogun Agbegba join together On gangan niyen E moo pe… Oo…In O ya - Oo…In Oluwa to fi yi sike ara yin - Oo A ba yin kale dojo ale - In E o ni ku ni kekere - Oo Ee lo ra yin gbo dandan - In Ninu ola, ola on alaafia Ayo yin a wa kale Ee ni kabamo Ee bako, ee babo Ee kole mole, Ee rale mole Asiri yin o ni tu o laraye lowo Iko kan ii kejo lona E mo lo re, e mo boore Iko kan imo i kejo lona E mo lo re, e mo boore Sese lomode nyo meye Se se se se se se se se… Sese lomode nyo meye Gbogbo aye o ma yo moo yin Ise yin o ni dise moo yin lowo Ise yin o ni baraye ninu Edumare to mu yin pade ara yin Yio mu yin se alabapade ire Yio moo duro ti yin gboin gboin Gboin gboin gboin gboin…