Asa - Oré lyrics

Published

0 274 0

Asa - Oré lyrics

Ma ya lé mi iwo orè atojubo onilé Ma ya lé mi iwo orè agbok'oloko Ma ya lé mi awon orè adugbo Ma ya lé mi ma ya lé k'omo Orè ti mo mu bi aburo Orè, orè ti mo sé daara dara Orè ti mo fi nu hun Owa daami o tumi sita Odabi oro ano Bi oro ano Don't come to my house, Iwo orè éké adugbo Don't come to my house, Iwo orè adaléru Maya lé mi, orè kofeniferé Maya lé mio maya lé rara Isè ni mo wa lojo yi o Oko t'o fèmi si lè Ko ku lo wa sè sé La won mejéji, won bèrè isé kusé Won wuma omodé, won sé wun won Odabi oro ano Bi oro ano Ewa wo ija lo jo yen Ewa wo éro ton tu ta Ewa wo ara lojo yen Ejé rée ni le Ma ya le mi toro iyo Ma ya le mi toro ata Ma ya mi le rara Isé ku sé kun owo rè I don't want to see you no more