Asa - Iba lyrics

Published

0 535 0

Asa - Iba lyrics

Oru s? ileku, I wanna have some talk, with you-o Nitori r? mo s? lola Nitori r? mo s? sog? Nitori r? mo s? ra moto Mo wo l?, mo boluwa mi soro Nitori r? mo s? wa laiye Nitori r? mo s? wa so sara Nitori re moji lowuro Mo wo aye mi lo de ye ya Aa aho ha ha a ha Iba fi ele iba fi eledua Aa ho ho a ho Mo mo le ye mo boluwa mi soro Nitori re mo s? gbo Iroyin ayo lai so owo lai si nkan kan I ya oni layo la o o boluwa se wi be na lori Oh oh o wi kpe kim ma se beru So aho ho a ho a a ho Aa aho ha ha a ha Iba fi ele iba fun eledua mo wo le mo boluwa mi soro Ninu ikpon ju Ninu i damu be emi ba gbo ro ma wo l? ma boluwa mi soro b? emi o l? y? ba aye ba fi oju d? mi be emi oni ile ma wo le ma boluwa mi soro Aa aho ha ha a ha iba fi ele iba fun eledua iba o o o o mo wo le ye mo boluwa mi soro O o o mi Ninu ikpon ju Ninu idamu be mi ba gbo ro ma wo le ma boluwa mi soro mo o ni foju sunku mo o o o aye lo ja, orun ni ile ?ni a fi ba mi iba O O O