OGA
Verse 1
Oluwa iwo la tobijú
Oluwa iwó la lagbará
Alagba wi mí
Ologo juló
Mo gborúko re gá
Nitorí pé ogá
Chorus
Ogá gá gà gá oh
Ogá gá gà gá oh
Ogá gá gà gá oh
Oga ju orun ló
Ojí ji ji ji oh
Ojí ji ji ji oh
Ojí ji ji ji oh
Ojí ijílé orún
Ofé fe fe fe oh
Ofé fe fe fe oh
Ofé fe fe fe oh
Ofé jú ayé ló
Verse 2
Alàgbàda inó gà
Ogà oh
Asíwajú ogún laló gà
Ogà oh kinihun eye
Judah ga
Ogà oh
Bami ga jú orun lo
Oluwà yi gà ee
Oluwà yin ló
Oluwà yin fé
Repeat Chorus