O de o Olagbaja ma tun de o O bo sokoto k' enu e da'le Olagbaja ma tun de o Chant: Olagbaja nbe lode Eru o le ba wa o Olagbaja nbe lode Eru o le ba wa o Chant: Ko i ye won
Yio ye won lola Chant: Olagbaja ma tun de o O bo sokoto k'enu e da'le Olagbaja ma tun de o Chant: Wa fun wa ni'lu Ilu orin Wa fun wa ni'lu Ilu orin