Aa, lowe lowe la mi nlu'lu agidigbo Ologbon mi a gbo Omoran lo ma ye Ahaa, te'ti e sile ko o k'ogbon o Ilu nro kango kango Agidigbo nso'ro Oro ijinle Ah, iwo nmi'ri O nse beeni, beeni Ose ayan ‘Mode yi oro lo so, oro lo so, oro lo so, oo puro o Bee ke oo gbo'lu Oo gbo nothing Bee ke oo ma de gbo ohun t'aye nwi o Nje ka loo gbo ni Boya se loba yari pata Ka loo gbo ni boya se lo ba ki ija mole Ka loo gbo ni Boya se lo ba so gele Dooja o dain dain Se pe ko lee dun ni Ohun oluware o gbo O ba f'eti sile Ko ko die nibe Boya won nbu e Boya won nki e Onilu yi sora e Mama dogbon bu mi o Ilu gbogbo ko loriki Sora e Ee, lowe lowe la mi nlulu agidigbo Ologbon mi a gbo Omoran lo ma ye O ba te'ti e sile koo kogbon o Agidigbo nsoro oro ijinle agidigbo Chants: Gbomo gbomo, gbomo gbomo Ana o gbe kan opelenge Oni o gbe kan fati bum bum
Ojo ojokan nbo O si maa gbe O si maa gbe Ojo ojokan o si maa gbe jombo Fine baby to ndan O kun soju O kun sete Lai sojuju Calabar Mama mu mi dese Mo ni'yawo mi si'le Mi o si le gb'oju Mi o le gb'oju mi kuro Boo ba be careful Wa tele mi dele E pagbo yimika Agidigbo Yimika E pagbo yimikaa Yimika Ta lo nsoro Nsoro Ta lo ngboro Ngboro Enit'o leti To leti To f'arabale F'arabale Ki lagidigbo wi Gidigbo wi Oro ijinle Ijinle E pagbo yimikaa Agidigbo Yimika Agidigbo O se mode yi Nje ka loo gbo ni Boya se lo be yari pata Ka loo gbo ni Boya se lo ba ki ija mole Ka loo gbo ni Boya se lo ba so gele dooja o dain dain Aaa agidigbo nsoro Oro ijinle Un hun, un hun, onilu yi sora e Ah mama dogbon bu mi o Mo mo pe'lu gbogbo ko loriki Ayan sora e Sora e, sora e o Ma ma dan mi wo Ayan sora e Aa, aa, agidigbo nsoro Oro ijinle