Aa - Broda Olé lyrics

Published

0 382 0

Aa - Broda Olé lyrics

Oh ah! mo gbon pké Eyin ni broder oké Eyin le ko mo mi lo lé Oh ah! mo gbon pké Eyin ni sista oké Eyin le nfe broder olé Iya sidi oni diri mi Sisi uche egbon ore mi Awon lo ran mi wa o Bobo musa oni réké wa Iya mulika olomo méjé Awon lo ron mi wa o Éyi ko nsoro èrin Èma jè nso fe anybody Am talking to you, talking To you Tori olorun mo be o Éma je nse fe anybody Am talking to you, talking to you